English to Yoruba: My Bio | |
Source text - English My name is Charity, I am a nurse and also a freelancer. An indigene of the great Yorubaland and I was born in Nigeria.
My name means Love and I love the name so much.
I love reading, cooking, sewing, singing and visiting new places. | Translation - Yoruba Orúkọ mi ni Charity, isẹ Nọọsi ni mo yàn láàyò mò sí ma nṣiṣe lórí ẹ̀rọ ayélujára. Ọmọ Yorùbá ni mo je, omo bíbí ile Naijiria sì nimi. Ìtumò orúko mi ni 'Ìfẹ́', mọsi fẹràn orúko na lopolopo.
Awọn nkan ti mọ fẹràn láti má ṣe ni ìwé kíkà, oúnjẹ síse, aṣọ rírán, orin kíkọ ati ki n máa ṣabẹwo ilé tuntun. |